Category: YORUBA

ASAYAN EEWO ILE YORUBA

OFIN         Ofin je ona kan ti o fa asa tabi mu asa wa,  paapaa julo eewo. Ofin je ki a ni awon ilana ati agbekale oniriru ofin ati asa, eyi gan ni o mu ki ofin yato si ara pelu oniriru asa ni awujo paapaa ni iwo ila orun Afirika ati Naijeria eyi ti […]