ASAYAN EEWO ILE YORUBA

OFIN

        Ofin je ona kan ti o fa asa tabi mu asa wa,  paapaa julo eewo. Ofin je ki a ni awon ilana ati agbekale oniriru ofin ati asa, eyi gan ni o mu ki ofin yato si ara pelu oniriru asa ni awujo paapaa ni iwo ila orun Afirika ati Naijeria eyi ti Yoruba je okan gbogi lara won.

Ti a ba soro nipa ofin a ko le se alaisoro nipa asa nitori pe ilana agbakale ofin ni n mu asa wa paapaa julo eewo yala ni Orile ede kan tabi awon eya kan ofin to ba wa ni awujo bee gbodo je eyi ti o fesemule daadaa.

        Nigba miran ofin kan a tun maa wa fun esin tabi ohun ti a gbagbo ninu re fun apeere ofin fun awon Onigbagbo, musulumi ati elesin abalaye. Ofin wonyi jeyo fun ilana tabi itoni fun eda eniyan eyi to si n se itoni paapaa fun igbe aye rere ati alafia pelu alabagbe, Gege bi ati se mo pe ilu ti ko ba si ofin ko si ese eyi tumo si pe ni bi ti ofin ba wa dandan ni ki ese wa nibe, nipa eyi ni ofin fi wa fun igbayegbadun eniyan lawujo lai si awon iwa ti o le tabuku awujo won nipa se eyi ofin n se afihan awon asa ni oniruru ona ati awon ijiya ti o tele fun eni to ba tapa si awon ofin.

        Bakana ni awon ofin wa fun oniruru nkan lawujo yala fun aso wiwo oye jije tabi oba jije, ati wipe idalu ni iselu gege bi oro Yoruba ti wi.

EEWO

        Eewo je okan ninu awon asa ni ile Yoruba, eewo je okan lara awon asa ibile tabi adayeba. Asa ni eewo o si tun je okan ninu awon asa ti o n fi emi igbagbo han laarin awon Yoruba, nitori o je awon ohun ti Yoruba gbagbo pe a ko gbodo se ki a ma ba a ri ayorisi ti ko dara.

How to get complete project materials


WE ALSO ACCEPT BITCOIN:  1622QAeaHXnWPArT7bBC6zX4ywsu5t3PmQ Step 1: make payment of N2,500 to any of the bank below


NAME:                       TITUS AYANI SOLA
BANK:                       FIRST BANK PLC
ACCT NO:                  3111741042
ACCOUNT TYPE:       SAVINGS
AMOUNT:                  N2,500

NAME:                       TITUS AYANI SOLA


BANK:                       ACCESS BANK
ACCT NO:                  1244558139

NAME:                       TITUS AYANI SOLA


BANK:                       GTB BANK
ACCT NO:                  0262412831
ACCOUNT TYPE:       SAVINGS

STEP 2: AFTER PAYMENT SEND THE PROJECT TOPIC AND YOUR MODE OF DELIVERY (EMAIL ADDRESS OR WHATSAPP) TO 08063666753

CLICK ON THE IMAGE BELOW TO REQUEST FOR MATERIAL

WE ALSO ACCEPT BITCOIN:  1622QAeaHXnWPArT7bBC6zX4ywsu5t3PmQ

Updated: 24th April 2019 — 3:29 pm