ORI KINNI
IFAARA
Idi ti mo fi yan ori oro yii laayo ni lati mo isoro ti o n koju awon akekoo elede keji lori girama ede Yoruba.
Niwon igba ti o je pe girama ni awon ofin ati ilana ti ede kookan maa n tele ninu siso tabi akosile iru ede bee, ti a ba wo ohun ti girama je, a o ri wipe okan lara ise ti o ye ki gbogbo akekoo ede mo daradara ni.
O ye ki akekoo kookan ni imo lori ede meteeta ti ijoba ti fi kale. Hausa, Igbo ati Yoruba yato si ede abinibi wa, bi o ba ri bee iwadii ti fihan pe girama ni ipilese ede nitoripe ibe ni a ti n se ayewo ihun ede, eya gbolohun, ihun igbolohun ati bee bee lo.
IPILE ISE IWADII
Ni opo ile-eko olukoni agba nibi ti a ti n ko ede Yoruba gege bi ede kinni ati akokunteni ni won koju isoro olokan-ojokan, opo awon akekoo wonyii ni won ro pe ede yii le pupo, ti o si dabi eni pe ati ko eko yege ninu re di eni ori ba koyo, won gbagbe pe bakan naa ni gbogbo ede ri ni agbaye, iha ti a ko si okookan won lo yato.
Awon akekoo elede keji je omo ti ko ni imo rara ninu ede ti o fe ko, won kii se omo bibi Yoruba, won kii se omo ti a wo ni awujo Yoruba.
Siwaju si, olusewadii ri wipe awon akekoo elede keji wonyii maa n bere ibeere lowo awon akekoo kinni ti eka eko ede Yoruba lori awon isoro ise ti won n ko paapaa lori girama.
AKOSILE ISORO IWADII
Orisirisi isoro ni mo koju ninu ise iwadii mi yii, lara awon isoro ti mo koju ninu ise iwadii yii ni:
- Ko si akoko pupo lati se ofintoto pupo ninu awon isoro ti awon akekoo elede keji n koju.
- O nami ni opolopo akoko ki n to le se awari awon akekoo ede Yoruba ti oro yii kan gbongbon.
- Isoro miran ni isoro owo, ko si owo pupo lati le mu ki ise iwadii naa ya.
- Ko to di wipe mo se awari awon oluko agba ti n ko ede Yoruba paapaa julo awon ti n sise lori girama ede Yoruba, o nami ni akoko die.
- Isoro miran ni a ti le tumo ede adugbo ti awon ti mo fi oro wa lenu wo so si ede Yoruba ajumolo.
- Isoro miran ni aini ifowosowopo ti o ye lati odo awon akekoo ti mo fi oro wa lenu wo.
How to get complete project materials
Step 1: make payment of N3000 to any of the bank below
NAME: JOLLERTEX GLOBAL SERVICES
BANK: WEMA BANK PLC
ACCT NO: 0124522105
AMOUNT: N3000
NAME: TITUS AYANI SOLA
BANK: FIRST BANK
ACCT NO: 3111741042