ODUN AGBON NI ILU IGOBA TI EKU IJOBA IBILE AKURE NI IPINLE ONDO

ORI KIN-IN-NI

IFAARA

          Niwon igba ti ko tii si enikeni to titi se ise lori odun agbon yii ni ilu igoba to si je pe bi awon agbaagba ilu ti n ku lo tan tie sin musulumi ati ti omoleyin Kristi ti n gbode kan to be e to fi je pe o fe maa pa asa ibile ti wa run, mo funra pe ohun nlanla lo maa mu wa bi iru odun pataki bayii ba le nti mo wa lara ti ko si ni si akosile Kankan fun awon omo wa to nbo lehinwa ola ati fun anfani elomiran ti ko ba wa se odun yii ri lati mo bi a ti n se odun agbon ni ilu igoba ati awon anfaani to wa ninu odun yii fun awon ara ilu lapapo niwon igba to je pe ki I se odun idile kan ni ni pato bi ko se odun ilu lapapo.

Nitori naa mo gbe ise iwadii yii dide laakoko ti mo mo pe ati ri oro gba sile lenu awon kookan to ku to je agbateru odun yii ko ni nira rara.

ONA IWADII

          Oniruru ona iwadii ni awon ti n se iise iwadii maa n mulo. Ohun ti a o se amulo re ninu ise iwadii yii ni iforowani lenu wo lodo awon agba ati awon oloye ilu. Bakan naa ni a o kan si awon ti n ko pa ninu odun yii gan ti a bale ri okodoro bi won ti n se odun yii lati odo awon ti n se fun ara won.

ERONGBA

          Idi pataki ti o nu mi dagba le sise iwadii lori I koko oro yii pin si ona meji. Ni ona kin-in-ni bi odun yii ti se pataki to ko si akosile kan ti ari toka si lori re siwaju askio yii.

A woye pe ti ko ba ni akosile tie sin igbagbo ti n le awon odun ibile wole balee wole laisi akosile, yoo di ohun igbagbe yoo dabi omi ti o san koja ni ori apata sugbon pelu akosile yii yoo le wa titi lailai.

Ni ona keji a woye pe lori ise yii yoo le so eso yoo je ise ti awon ase wadii ojo iwaju yoo maa ri to ka si yoo je ipile fun awon ohun ti akosile tokaasi tan nipa odun yii yoo si ran awon oluwadi ojo iwaju lowo.

AAYAN AWON OMORAN

          Gege bi Daramola ati Jeje se so ninu iwe won Awon Asa ati Orisa ile Yoruba ti won se ni  1970. Won fi ye w ape “Okanlenirin wo irunmole tabi orisa ni Olodumare ran wa si aye. Bakan naa ni ko si ilu kan ni ile Yoruba ti ko ni yala ikan tabi meji ti won n bo laarin awon orisa tabi irunmole wonyii boya ni odoodun tabi odun meta-meta sira won tabi ju bee lo. Won te siwaju lati fi ye w ape opo ninu awon orisa wonyii lo ti fi igba kan je eniyan tele ri ki won to di eni ti a n bo ati eni ti a n sin nitori agbara ti won ni nigba ti won wa ni ile aye”.

How to get complete project materials


WE ALSO ACCEPT BITCOIN:  1622QAeaHXnWPArT7bBC6zX4ywsu5t3PmQ Step 1: make payment of N2,500 to any of the bank below


NAME:                       TITUS AYANI SOLA
BANK:                       FIRST BANK PLC
ACCT NO:                  3111741042
ACCOUNT TYPE:       SAVINGS
AMOUNT:                  N2,500

NAME:                       TITUS AYANI SOLA


BANK:                       ACCESS BANK
ACCT NO:                  1244558139

NAME:                       TITUS AYANI SOLA


BANK:                       GTB BANK
ACCT NO:                  0262412831
ACCOUNT TYPE:       SAVINGS

STEP 2: AFTER PAYMENT SEND THE PROJECT TOPIC AND YOUR MODE OF DELIVERY (EMAIL ADDRESS OR WHATSAPP) TO 08063666753

CLICK ON THE IMAGE BELOW TO REQUEST FOR MATERIAL

WE ALSO ACCEPT BITCOIN:  1622QAeaHXnWPArT7bBC6zX4ywsu5t3PmQ

Updated: 20th June 2017 — 7:49 pm